AYOMIPOSI AJAYI Giáo viên dạy về kiến thức nâng cao của Yoruba
Sọ yòrùbá pẹlu irọ̀rùn
999Buổi học Giao tiếp Yoruba đã hoàn thành
Giới thiệu
Có thể nói
YorubaBản ngữ
Tiếng AnhBản ngữ
Dịch thuật AI
Yorùbá là èdè tí ó dùn sí, ó sì ń gbé àṣà àti ìṣe wa lára. Orísísi ònà ní èdè náà ti gbé wa lára bíi tí orin, ìkíni àti nípa èro àmọ̀ràn. Ṣùgbọ́n kámá purọ, a gbọ́dọ̀ kó Yorùbá kí a tó lè sọ, ìdí tí mo ṣe jẹ́ olùkọ́ ni yí.
Orúkọ mi ni Ayomiposi Ajayi, ọmọ bíbí Nigeria ni mo jẹ́, mo jẹ́ Yorùbá, ìpínlẹ̀ Ekiti ni mo ti wá. Kíkó èdè Yorùbá jẹ́ ohun tí mo fẹ́ràn, mo sì ti ń kó èdè Yorùbá fún ọdún mẹ́wàá pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣeyọrí láàárín àwọn àkékò mí láìsí ìdíwọ́ tàbí ìjìkàlẹ̀.
Mo jẹ́ẹ́ ní inú ìdánwò ní ilé ẹ̀kọ́ gíga pẹ̀lú ẹ̀sì tí ó dára jù lọ, mo sì ti kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkékò ní ilé ẹ̀kọ́ alákòbéré àti ilé ẹ̀kọ́ gíga kí tó tèsíwájú pẹ̀lú ẹ̀kọ́ mi ní váàsítì.
Ẹ jé ká sàwárí èdè Yorùbá papọ̀;
Ọnà tí n ó máa gbà kọ́ àwọn akékò mi ní láti máa kọ́ wọn ní àwọn nnkan tí wọ́n yóò fi máa sòrò, tí wọ́n bá ti lè sòrò a ó má lọ orísirísi òrò ní gbólóhùn, a ó sì má túnmò òrò sí èdè Gẹ̀ẹ́sì àti sí èdè Yorùbá.
Àwọn ẹ̀kọ́ wa yóò máa mú ọ́rùn wa yá, yóò sì tún kó wa mọ́ra pẹ̀lú
Orísirísi ìwé ni a ó pèsè fún àwọn akékò láti lè mú ẹ̀kọ́ wa yá
Awon akéekó mi ti n so yorùbá dáradára, wón si ti lé ní ogórún, èyí jé àmì ìdánilójú pé tìre yóo seése.
láìpé ìwo naa yóo ma so èdè yorùbá láìsí ìdíwó.
Yára láti fi orúko sílè pèlú wa fùn kilaasì
Xem toàn bộ phần giới thiệu
Tìm hiểu thêm về bài học này
Nhiều khung giờ trống hơn
Chọn càng nhiều buổi học, ưu đãi càng lớn, xem chi tiết bên dưới hoặc trong giỏ hàng!
Thời gian có sẵn
Xem toàn bộ lịch học
Có thể tải video buổi học
Bạn có thể tải về video từ các khóa học 1 kèm 1 trong vòng một năm sau khi kết thúc khóa, giúp nâng cao trải nghiệm học tập!
(Chỉ áp dụng thưởng này cho học viên bật chức năng ghi hình lớp học)
Rất tốt khi kết hợp giữa học có cấu trúc và giao tiếp. Hoàn hảo cho con tôi tuổi teen, người đang muốn học ngôn ngữ theo cách vừa có cơ hội luyện nói vừa có định dạng quen thuộc như khi học ngôn ngữ ở trường.